
ADÚRÀ-ORIN ÈSÙ-BÀRÀ
(Rezos cantados de Exu-Bará)
Oríkì
(Alabanza)
ONÍLÙ (tamborero)
Ajúbà Bàrà-Légbà, Olóde, Èsù-Lonà, Bàrà Dage burúkú, Lànà Bàrà’ Jelù. Làlúpo, Èsù-Bàrà!
(Respetamos a Bará, dueño del látigo, de los campos, Exu en el camino, Bará que corta el mal, abre los caminos Bará mensajero del tambor. ¡Abre señor del dendé Exu-Bará!)
DÁHÙN (Responder) - Làlúpo! (Abre señor del dendé)
TOQUE NAGÔ
Onílù: Èsù Èsù Olóde
Dàhún: Èsù o Bará lànà
Onílù: Bàrà Olóde
Dàhún: Èsù o Bará lànà
Onílù: Bàrà Èsù
Dàhún: Bàrà
Onílù: Lànà Èsù
Dàhún: Bará
Onílù: Lodé Èsù
Dàhún: Bará
Onílù: Èsù Olóde
Dàhún: Èsù o bará lànà
Onílù: Bàrà Olóde
Dàhún: Èsù o bará lànà
Onílù: Bàrà Èsù
Dàhún: Bàrà
Onílù: Lànà Èsù
Dàhún: Bará
Onílù: Lodé Èsù
Onílù: Amachere onibá Èsù abanada, amachere onibá Èsù abanada.
Dàhún: Amachere onibá Èsù abanada, amachere onibá Èsù abanada.
Onílù: Amachere onibá Èsù abanada, amachere onibá Èsù abanada.
Dàhún: Amachere onibá Èsù abanada, amachere onibá Èsù abanada.
Onílù: Ogum ademi chechemirê
Dàhún: Bara ademi chechemirê
Onílù: Ogum ademi chechemi-Bará
Dàhún:Bara ademi chechemirê
Onílù: Èsù yá lànà fuá
Dàhún: Èsù yá lànà fun malé
Onílù: Èsù yá lànà ile
Dàhún: Èsù yá lànà fun malé
Onílù: Èsù yá lànà fuá
Dàhún: Èsù yá lànà fun malé
Onílù: Èsù yá lànà ile
Dàhún: Èsù yá lànà fun malé
Onílù: Bará Èsù mérin
Dàhún: Èsù b’erin, Èsù mérin loná
Onílù: Bara Èsù mérin
Dàhún: Èsù b’erin, Èsù mérin loná
Onílù: Bará Èsù mérin
Dàhún: Èsù b’erin, Èsù mérin lona
Onílù: Bara Èsù mérin
Dàhún: Èsù b’erin, Èsù mérin lona
Onílù: Èsùabana bana Èsù abana é
Dàhún:Èsùabana bana Èsù abana é
Onílù: Èsùabana bana Èsù abana é
Dàhún:Èsùabana bana Èsù abana é
Onílù: Aé àèo ní Bàrà ó, aé àèo ní Bàrà amacelo Ogun ló, amacelo Ogun lá aé àèo ní Bàrà ó
Dàhún: Aé àèo ní Bàrà ó, aé àèo ní Bàrà amacelo Ogun ló, amacelo Ogun lá aé àèo ní Bàrà ó
Onílù: Aé àèo ní Bàrà ó, aé àèo ní Bàrà amacelo Ogun ló, amacelo Ogun lá aé àèo ní bàrà ó
Dàhún: Aé àèo ní Bàrà ó, aé àèo ní Bàrà amacelo Ogun ló, amacelo Ogun lá aé àèo ní Bàrà ó
Onílù: Oni-Bará olereo
Dàhún: Aé àèoni-Bàrà
Onílù: Oia Oia
Dàhún: Oia ó elefá
Onílù: Èsù dé mí modí-Bara, Èsù á jó modipaim
Dàhún: Èsù dé mí modí-Bara, Èsù á jó modipaim
Onílù: Èsù dé mí modí-Bara, Èsù á jó modipaim
Dàhún: Èsù dé mí modí-Bara, Èsù á jó modipaim
Onílù: ole Bàrà èle ó! ole Bàrà èle ó! Motí-Bara ó eléfà epo!
Dàhún: ole Bàrà èle ó! ole Bàrà èle ó! Motí-Bara ó eléfà epo!
Onílù: ole Bàrà èle ó! ole Bàrà èle ó! Motí-Bara ó eléfà epo!
Dàhún: ole Bàrà èle ó! ole Bàrà èle ó! Motí-Bara ó eléfà epo!
Onílù: Bàrà óo anaraue á Esu Lana, Bàrà óo anaraue á Èsù Lana, amadeconi coni Bàrà o talabò Bàrà oelefa Esu lana
Dàhún: Bàrà óo anaraue á Esu Lana, Bàrà óo anaraue á Esu Lana, madeconi coni Bàrà o talabò Bàrà oelefa Èsù Lana
Onílù: Bàrà óo anaraue á Èsù Lana, Bara óo anaraue á Èsù Lana, amadeconi coni Bara o talabò Bàrà oelefa Esu lana
Dàhún: Bàrà óo anaraue á Esu Lana, Bàrà óo anaraue á Èsù Lana, amadeconi coni Bara o talabo Bàrà oelefa Esu lana
Onílù: Bàrà la mó jecum Ioda, Bàrà la mó jecum Ioda, Bàrà-rum eco barárundeo Bàrà la mó jecum Ioda, Bàrà la mó reum
Dàhún: jecum Ioda
Onílù: Bàrà la mó reum
Dàhún: jecum Ioda
Onílù: e papainhale
Dàhún: e papainhale
Onílù: e papainhale
Dàhún: e papainhale
Onílù: Èsù lànà fò mi o, Bàrà lànà fun malè o!
Dàhún: Èsù lànà fò mi o, Èsù lànà fun malè!
Onílù: Èsù lànà fò mi o, Bàrà lànà fun malè
Dàhún: Èsù lànà fò mi o, Èsù lànà fun malè!
Onílù: A Làlúpao
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: A Làlúpao
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: ay oke bara
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: Bàrà Bàrà
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: àlúpo e Bara
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: A Làlúpao
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: Bara esu lode
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: Bara esu lona
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: ay oke bara
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: e Bàrà Bàrà
Dàhún: àlúpa yé màá
Onílù: soo soni pado
Dàhún: gan gan gan gan soni pado
Onílù: Bara no eco soni pado
Dàhún: gan gan gan gan soni pado
Onílù: soo soni pado
Dàhún: gan gan gan gan soni pado
Onílù: Bàrà no eco soni pado
Dàhún: gan gan gan gan soni pado
Onílù: esu Bàrà yà b’odù màá sànà bò rè Elegba
Dàhún: O lè Bàrà yà b’odù màá sànà bò rè Elegba
Onílù: O lè Bàrà y à b’odù,
Dàhún: á má k’èrè k’ewé lè ele yà b’odù, á má k’èrè k’ewé
Onílù: ’odù máa dó k’èrè k’èrè k’èrè dó k’orò k’orò k’orò, dó k’èrè k’èrè k’èrè eresum Elégbà
Dàhún: ’odù máa dó k’èrè k’èrè k’èrè dó k’orò k’orò k’orò, dó k’èrè k’èrè k’èrè eresum Elégbà
Onílù: ’odù máa dó k’èrè k’èrè k’èrè dó k’orò k’orò k’orò, dó k’èrè k’èrè k’èrè eresum Elégbà
Dàhún: ’odù máa dó k’èrè k’èrè k’èrè dó k’orò k’orò k’orò, dó k’èrè k’èrè k’èrè eresum Elégbà
Onílù: Legba Ogum ferere
Dàhún: Ogum
Onílù: Legba Ogum ferere
Dàhún: Ogum
Onílù: Legba Ogum ferere
Dàhún: Ogum
|